Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ti Kínamónì, àti ti onírúurú ohun olóòórun dídùn, àti ti ohun ìkunra, àti tí tùràrí, àti ti ọtí wáìnì, àti ti oróro, àti ti ìyẹ̀fun dáradára, àti ti àlìkámà, àti ti ẹran ńlá, àti ti àgùntàn, àti ti ẹ̀sin, àti ti kẹ̀kẹ́, àti ti ẹrú, àti ti ọkàn ènìyàn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 18

Wo Ìfihàn 18:13 ni o tọ