Wọ́n ó dúró ní òkèrè réré nítorí ìbẹ̀rù iṣẹ́ oró rẹ̀, wọn ó máa wí pé:“ ‘Ègbé! Ègbé, ni fún ìlú ńlá náà,Bábílónì ìlú alágbára nì!Nítorí ní wákàtí kan ni ìdájọ́ rẹ dé!’