Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èkínní sì lọ, ó sì tú ìgò tirẹ̀ sí orílẹ̀ ayé: egbò kíkẹ̀ tí ó sì díbàjẹ́ sì dá àwọn ènìyàn tí ó ní àmì ẹranko náà, àti àwọn tí ń foríbalẹ̀ fún àwòrán rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:2 ni o tọ