Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 16:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mọ̀nàmọ́ná sì kọ, a sì gbọ́ ohùn, àrá sì sán, ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá sì ṣẹ̀, irú èyí tí kò sẹ̀ ri láti ìgbà tí ènìyàn ti wà lórí ilẹ̀, irú ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá bẹ́ẹ̀, tí ó sì lágbára tóbẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:18 ni o tọ