Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rí àmì mìíràn ní ọ̀run tí ó tóbi tí ó sì ya ni lẹ́nu, àwọn ańgẹ́lì méje tí ó ni àwọn ìyọnu méje ìkẹ́yìn, nítorí nínú wọn ni ìbínú Ọlọ́run dé òpin.

Ka pipe ipin Ìfihàn 15

Wo Ìfihàn 15:1 ni o tọ