Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì tẹ ìfúntí náà lẹ́yìn òde ilú náà, ẹ̀jẹ̀ sì ti inú ìfúntí náà jáde, ó sì ga sókè dé okùn ìjánu ẹṣin, èyí tí ìnàsílẹ̀ rẹ to ẹ̀gbẹjọ̀ ibùsọ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 14

Wo Ìfihàn 14:20 ni o tọ