Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì lé dírágónì ńlá náà jáde, ejò láéláé ni, tí a ń pè ni Èṣù, àti Sàtanì, tí ń tan gbogbo ayé jẹ: a sì lé e jù sí ilẹ̀ ayé, a sì lé àwọn ańgẹ́lì rẹ̀ jáde pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:9 ni o tọ