Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì na ọwọ́ rẹ̀ sí i, ó fà á dìde; nígbà tí ó sì pe àwọn ènìyàn mímọ́ àti àwọn opó, ó fi i lé wọn lọ́wọ́ láàyè.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:41 ni o tọ