Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ-ẹ̀yìn kan sì wà ní Dámásíkù, tí a ń pè ni Ananíyà! Olúwa sì wí fún un lójúran pé, “Ananíyà!”Ó sì wí pé, “Wò ó, èmi nìyí, Olúwa.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:10 ni o tọ