Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni wọ́n fún àwọn ọkùnrin kan ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀, kí wọn ń wí pé, “Àwa gbọ́ tí Sítéfánù ń sọ ọ̀rọ̀-òdì sí Mósè àti sí Ọlọ́run.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:11 ni o tọ