Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sí wí fún un pé, “È é ṣe ti ẹ̀yin fohùn sọ̀kan láti dán Ẹ̀mí Mímọ́ wò? Wò ó, ẹsẹ̀ àwọn tí ó sìnkú ọkọ rẹ ń bẹ lẹ́nu ọ̀nà, wọn ó sì gbe ìwọ náà jáde.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:9 ni o tọ