Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ọkùnrin yìí ni Júdà ti Gálílì dìde ni àkókò kíka àwọn ènìyàn, ó sì fa ẹni púpọ̀ lẹ́yìn rẹ̀; òun pẹ̀lú ṣègbé; àti gbogbo iye àwọn tí ó gba tirẹ̀ ni a fọ́nká.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:37 ni o tọ