Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí, àti gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀mí Mímọ́ ti se ẹlẹ́rìí pẹ̀lú, tí Ọlọ́run fifún àwọn tí ó gbà á gbọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:32 ni o tọ