Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí nínú àwọn ìyókù tí ó jẹ́ gbìyànjú láti darapọ̀ mọ́ wọn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn ń fi ọ̀wọ̀ gíga fún wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:13 ni o tọ