Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní nítòótọ́ ní Hẹ́rọ́dù, àti Pọ́ńtíù Pílátù, pẹ̀lú àwọn aláìkọlà àti àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì kó ara wọn jọ ní ìlú yìí láti dìtẹ̀ sí Jésù Ìrànṣẹ́ mímọ́ rẹ, ẹni tí ìwọ ti fi òróró yàn,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:27 ni o tọ