Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì kíyèsí ìgboyà Pétérù àti Jòhánù, tí wọ́n mọ̀ pé, aláìkẹ́kọ̀ọ́ àti òpè ènìyàn ni wọn, ẹnu yà wọ́n, wọ́n sì wòye pé, wọ́n ti ń bá Jésù gbé.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:13 ni o tọ