Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù wí pé, “Góòlù àti fàdákà èmi kò ní, ṣùgbọ́n ohun tí mo ní èyí náà ni mo fifún ọ: Ní orúkọ Jésù Kírísítì ti Násárẹ́tì, dìde kí o sì máa rìn.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:6 ni o tọ