Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ni ọmọ àwọn wòlíì, àti ti májẹ̀mú tí Ọlọ́run ti bá àwọn baba yín dá nígbà tí ó wí fún Ábúráhámù pé, ‘Láti ipasẹ̀ irú àwọn ọmọ rẹ̀ ni a ó ti bùkún fún gbogbo ìdílé ayé.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:25 ni o tọ