Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè wí pé, ‘Olúwa Ọlọ́run yín yóò gbé wòlíì kan dìde fún yín nínú àwọn arákùnrin yín, bí èmi; òun ni ẹ̀yin yóò máa gbọ́ tirẹ̀ ní ohun gbogbo tí yóò máa sọ fún un yín.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:22 ni o tọ