Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n báyìí ni Ọlọ́run ti se ìmúṣẹ àwọn ohun tí ó ti sọ tẹ́lẹ̀ láti ẹnu gbogbo àwọn wòlíì pé, Kírísítì rẹ̀ yóò jìyà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:18 ni o tọ