Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ohùn wọn kò ṣọ̀kan láàrin ara wọn, wọ́n túká, lẹ́yìn ìgbà tí Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ kan pé, “Ẹ̀mí Mímọ́ sọ òtítọ́ fún àwọn baba yín nígbà tí ó sọ láti ẹnu wòlíì Àìṣáyà wí pé:

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:25 ni o tọ