Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì wí fún un pé, “Àwa kò rí ìwé gbà láti Jùdíà nítorí rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan nínú àwọn arákùnrin tí ó ti ibẹ̀ wá kò ròyìn, tàbí kí ó sọ̀rọ̀ ibi kan sí ọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:21 ni o tọ