Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ilẹ̀ sí mọ́, wọn kò mọ́ ilẹ̀ náà; ṣùgbọ́n wọn rí apá odò kan tí ó ní èbúté, níbẹ́ ni wọ́n gbérò, bóyá ó le ṣe é ṣe láti mu ọkọ̀ gúnlẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:39 ni o tọ