Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ilẹ̀ ń mọ́ bọ̀, Pọ́ọ̀lù bẹ gbogbo wọn kí wọn jẹun díẹ̀, ó wí pé, “Òní ni ó di ìjẹrìnlá tí ẹ̀yin ti ń rétí, ti ẹ kò dẹkun gbígbaàwẹ̀, tí ẹ kò sì jẹun.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:33 ni o tọ