Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì wọn òkun, wọ́n rí i ó jìn ní ogún ìgbọ̀nwọ́, nígbà tì í wọ́n sún ṣíwájú díẹ̀, wọ́n sì tún wọn òkun, wọn rí i pé ó jìn ni ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ẹ̀dógùn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:28 ni o tọ