Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgírípà sì wí fún Pọ́ọ̀lù pé, “Ǹjẹ́ ìwọ ró pé ìwọ́ fi àkókò díẹ̀ yìí sọ mí di Kírísítìẹ́nì?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:28 ni o tọ