Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìkóríta yìí Fẹ́sítúsì kọ dí àwíjàre Pọ́ọ̀lù, ó wí lóhùn rara pé, “Pọ́ọ̀lù, orí rẹ dàrú; ẹ̀kọ́ àkọ́jù rẹ ti dà ọ́ ní orí rú!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:24 ni o tọ