Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

láti là wọ́n lójú, kí wọn lè yípadà kúrò nínú òkùnkùn sí ìmọ́lẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ agbára Sátanì ṣí Ọlọ́run, kí wọn lè gba ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀, àti ogún pẹ̀lú àwọn tí a sọ di mímọ̀ nípa ìgbàgbọ́ nínú mi.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:18 ni o tọ