Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà púpọ̀ ni mo ń fi ìyà jẹ wọ́n láti inú ṣínágọ́gù dé inú ṣínágọ́gù, mo ń fi tipá mú wọn láti sọ ọ̀rọ̀-òdì. Mo sọ̀rọ̀ lòdì ṣí wọn gidigidi, kódà mo wá wọn lọ sí ìlú àjèjì láti ṣe inúnibíni sí wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:11 ni o tọ