Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Fẹ́sítúsì ń fẹ́ láti ní ojúrere lọ́dọ̀ àwọn Júù, ó sì dá Pọ́ọ̀lù lóhùn, wí pe, “Ìwọ ń fẹ́ gòkè lọ sì Jerúsálémù, kí a sì ṣe ẹjọ́ nǹkan wọ̀nyí níbẹ̀ níwájú mi bí?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:9 ni o tọ