Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sì ta ẹ̀jẹ̀ Sítéfánù ẹlẹ́ríì rẹ sílẹ̀, èmi náà pẹ̀lú dúró níbẹ̀, mo sì ní ohùn sí ikú rẹ̀, mo sì ń se ìtọ́jú aṣọ àwọn ẹni tí ó pa á.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:20 ni o tọ