Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

mo sì rí Olúwa, ó ń sọ̀rọ̀ fún mi pé, ‘Kíá! Jáde kúrò ní Jerúsálémù kán-kán, nítorí wọn kì yóò gba ẹ̀rí rẹ nípa mi gbọ́.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:18 ni o tọ