Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo sí béèrè pé, ‘Kín ni kí èmí kí ó ṣe, Olúwa?’“Olúwa sì wí fún mi pé, ‘Dìde, kí o sì lọ sí Dámásíkù; níbẹ̀ ni a ó sì ti sọ ohun gbogbo fún ọ tí a yàn fún ọ láti ṣe.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:10 ni o tọ