Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ní ti àwọn aláìkọlà tí ó gbàgbọ́, àwa tí kọ̀wé, a sì ti pinnu rẹ̀ pé, kí wọn pa ara wọn mọ́ kúrò nínú ohun tí a fi rúbọ sí òrìṣà, àti ẹ̀jẹ̀ àti ohun ìlọ́lọ́rùn pa, àti àgbérè.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:25 ni o tọ