Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọjọ́ ìkínní ọ̀ṣẹ̀ nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn péjọ láti bu àkàrà, Pọ́ọ̀lù sì wàásù fún wọn, ó múra láti lọ ní ijọ́ kejì: ó sì fa ọ̀rọ̀ rẹ̀ gùn títí di àárin ọ̀gànjọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:7 ni o tọ