Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ nísinsìn yìí, ará, mo fi yín lé Ọlọ́run lọ́wọ́ àti ọ̀rọ̀ oore-ọfẹ́ rẹ̀, tí ó lè gbé yín dúró, tí ó sì lè fún yín ní ìní láàrin gbogbo àwọn tí a sọ di mímọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:32 ni o tọ