Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọn èmi kò ka ọkàn mi sí nǹkan rárá bi ohun tí ó sọ̀wọ́n fún mi àti iṣẹ́-ìránṣẹ́ tí mo tí gbà lọ́dọ̀ Jésù Olúwa, láti máa ròyìn ìyìn rere oore-ọ̀fẹ́ Ọ̀lọ́run.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:24 ni o tọ