Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti àwa sì ṣáájú, àwa sì ṣíkọ̀ lọ sì Ásósì, níbẹ̀ ni a ti lérò láti gba Pọ́ọ̀lù sínú ọkọ̀: nítorí bẹ́ẹ̀ ni ó tí pinnu rẹ̀, òun tìkararẹ̀ ń fẹ́ bá ti ọ̀nà-ẹṣẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:13 ni o tọ