Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sì gbọ́ ìró yìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn péjọ nínú ìdàmú, nítorí tí olúkúlùkù gbọ́ tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ ní èdè rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:6 ni o tọ