Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ìwọ kí yóò fi ọkàn mi sílẹ̀ ni isà-òkú,bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kí yóò jẹ́ kí Ẹni-Mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:27 ni o tọ