Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ bí nǹkan wọ̀nyí tí parí tan, Pọ́ọ̀lù pínnu nínú ẹ̀mí rẹ̀ pé, nígbà tí òun bá kọjá ní Makedóníà àti Ákáyà, òun ó lọ sí Jerúsálémù, ó wí pé, “Lẹ́yìn ìgbà tí mo bá dé ibẹ̀, èmi kò lè ṣàì má dé Róòmù pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:21 ni o tọ