Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí n lọ bẹ́ẹ̀ fún ìwọ̀n ọdún méjì; tóbẹ́ẹ̀ tí gbogbo àwọn tí ń gbé Éṣíà gbọ́ ọ̀rọ̀ Jésù Olúwa, àti àwọn Júù àti àwọn Gíríkì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:10 ni o tọ