Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì lọ kúrò níbẹ, ó wọ ile ọkùnrin kan tí a ń pé ní Títù Júsù, ẹni tí o ń sin Ọlọ́run; ilé rẹ̀ sì wà lẹ́gbẹ̀ Sínágógù tímọ́tímọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:7 ni o tọ