Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júù kan sì wà tí a ń pè ni Àpólò, tí a bí ni Alekisáńdíríà, ó wá sí Éféṣù. Ó nì ẹ̀bùn ọ̀rọ̀-sísọ, ó sì mọ ìwé mímọ́ púpọ̀;

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:24 ni o tọ