Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rí Júù kan tí a ń pè ní Àkúílà, tí a bí ni Pọ́ńtù, tí ó ti Ìtalì dé ní lọ́ọ́lọ́ọ́, pẹ̀lú Pírísíkílà aya rẹ̀; nítorí tí Kíláúdíù pàsẹ pé, kí gbogbo àwọn Júù jáde kúrò ní Róòmù. Ó sì tọ̀ wọ́n lọ láti rí wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:2 ni o tọ