Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nínú rẹ̀ ni àwa wà láàyè, tí a ń rìn kiri, tí a sì ní ẹ̀mí wa: bí àwọn kan nínú àwọn akéwì tí ẹ̀yin tìkarayín tí wí pé, ‘Àwa pẹ̀lú sì jẹ́ ọmọ rẹ̀.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:28 ni o tọ