Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí iyàn sì di púpọ̀, Pétérù dìde, ó sì wí fún wọn pé, “Ará, ẹ̀yin mọ̀ pé, láti ìbẹ̀rẹ̀ ni Ọlọ́run ti yàn nínú yín pé, kí àwọn aláìkọlà lè gbọ́ ọ̀rọ̀ ìyìn rere láti ẹnu mi, kí wọn sì gbàgbọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:7 ni o tọ