Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Pọ́ọ̀lù rò pé, kò yẹ láti mú un lọ pẹ̀lú wọn, ẹni tí ó fi wọn sílẹ̀ ni Páḿfílíà, tí kò sì bá wọn lọ sí iṣẹ́ náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:38 ni o tọ