Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru náà gan-an ti Héródù ìbá sì mú un jáde, Pétérù ń sùn láàrin àwọn ọmọ-ogun méjì, a fi ẹ̀wọ̀n méjì dè é, ẹ̀sọ́ sí wà lẹ́nu-ọ̀nà, wọ́n ń ṣọ́ túbú náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:6 ni o tọ