Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bánábà àti Ṣọ́ọ̀lù sì padà wá láti Jerúsálémù, nígbà ti wọ́n sì parí iṣẹ́ ìránṣẹ́ wọn, wọn sì mú Jòhánù ẹni tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Máàkù wá pẹ̀lú wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:25 ni o tọ